Loading ...
Sorry, an error occurred while loading the content.
 
 • Back
 • About Group

 • Join Group
No activity in last 7 days

Group Description

Egbe Yahoo! fun isoji, igbega ati itankale ede Yoruba. Ede aladun yi nikan ni awa ti a wa ninu egbe yi yio maa ko si ara wa. A ko fe Geesi, Faranse tabi edekede, bikose Yoruba.

Awon omo Yoruba nikan ko ni egbe yi wa fun. Gbogbo awon ti o feran ede Yoruba, ti won si fe ilosiwaju re, ni a pe lati ba wa dapo. Ibikibi ti o wu ki e ti wa, niwon'gbati e ba ti setan lati ba wa soro ni ede Yoruba nibiyi, a ki yin ku abo.

Yoruba dun un so!


Aworan: Opa Oranmiyan, Ile-Ife - © Molara Wood, 2004. Pelu ase lati owo ayaworan.

Group Information

 • 165
 • Yoruba
 • Dec 25, 2004
 • English

Group Settings

 • This is a restricted group.
 • Attachments are permitted.
 • Members cannot hide email address.
 • Listed in Yahoo Groups directory.
 • Membership requires approval.
 • Messages are not moderated.
 • All members can post messages.

Message History